Ẹ káàbọ̀ · Welcome

Ṣàwárí Àṣà àti Ìtàn Yorùbá Discover Yoruba Culture & Stories

Kọ́ ẹ̀kọ́, rẹ́rìn-ín, kí o sì ṣàwárí pẹ̀lú IbileWorld — èdè Yorùbá, oúnjẹ, ìrìn-àjò, àlọ́, àti ìtàn. Learn, laugh, and explore with IbileWorld - Yoruba language, food, travel, folktales, and history.

Àwọn Fídíò Tuntun Latest Videos

Òwe Yorùbá · Yoruba proverb

“Ilé la ń wò, ká tó sọ ọmọ lórúkọ.”

We look to the home before we name the child.

Who we are begins with where we come from. That's what ìbílẹ̀ means to us.

Kíláàsì Yorùbá Yoruba Language Classes

Ètò ìdánilẹ́kọ̀ọ́ èdè Yorùbá wa, fún àwọn olùbẹ̀rẹ̀ àti àwọn tí wọ́n gbọ́ Yorùbá ṣùgbọ́n tí wọ́n fẹ́ máa sọ ọ́ pẹ̀lú ìgboyà. Our Yoruba language coaching program with options for beginners and passive speakers who want to become confident speakers.

IbileWorldÀṣà • Oúnjẹ • Ìrìn-àjò • Àlọ́Culture • Food • Travel • Folktales
Kilaasi Yoruba